Jémíìsì 3:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Òun la fi ń yin Jèhófà,* Baba wa, síbẹ̀ òun la tún fi ń gégùn-ún fún àwọn èèyàn tí a dá ní “àwòrán Ọlọ́run.”+ 10 Ẹnu kan náà tí èèyàn fi ń súre ló tún fi ń gégùn-ún. Ẹ̀yin ará mi, kò yẹ kó máa rí bẹ́ẹ̀.+
9 Òun la fi ń yin Jèhófà,* Baba wa, síbẹ̀ òun la tún fi ń gégùn-ún fún àwọn èèyàn tí a dá ní “àwòrán Ọlọ́run.”+ 10 Ẹnu kan náà tí èèyàn fi ń súre ló tún fi ń gégùn-ún. Ẹ̀yin ará mi, kò yẹ kó máa rí bẹ́ẹ̀.+