-
1 Àwọn Ọba 17:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Èlíjà gbé ọmọ náà, ó gbé e sọ̀ kalẹ̀ láti yàrá orí òrùlé wá sínú ilé, ó sì gbé e fún ìyá rẹ̀; Èlíjà wá sọ pé: “Wò ó, ọmọ rẹ yè.”+
-
-
2 Àwọn Ọba 4:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Èlíṣà wá pe Géhásì, ó sì sọ pé: “Pe obìnrin ará Ṣúnémù náà wá.” Torí náà, ó pè é, ó sì wọlé wá bá a. Lẹ́yìn náà, ó sọ pé: “Gbé ọmọ rẹ.”+
-