Lúùkù 1:68 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 68 “Ẹ yin Jèhófà,* Ọlọ́run Ísírẹ́lì,+ torí ó ti yíjú sí àwọn èèyàn rẹ̀, ó sì ti gbà wọ́n sílẹ̀.+