Mátíù 27:54 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 54 Àmọ́ nígbà tí ọ̀gágun àti àwọn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ tí wọ́n ń ṣọ́ Jésù rí bí ilẹ̀ ṣe mì tìtì àtàwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀, ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi, wọ́n sì sọ pé: “Ó dájú pé Ọmọ Ọlọ́run nìyí.”+ Jòhánù 1:49 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Nàtáníẹ́lì dá a lóhùn pé: “Rábì, ìwọ ni Ọmọ Ọlọ́run, ìwọ ni Ọba Ísírẹ́lì.”+
54 Àmọ́ nígbà tí ọ̀gágun àti àwọn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ tí wọ́n ń ṣọ́ Jésù rí bí ilẹ̀ ṣe mì tìtì àtàwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀, ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi, wọ́n sì sọ pé: “Ó dájú pé Ọmọ Ọlọ́run nìyí.”+