Jòhánù 2:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àmọ́ Jésù ò gbára lé wọn, torí pé ó mọ gbogbo wọn, 25 kò sì nílò kí ẹnikẹ́ni jẹ́rìí nípa èèyàn, torí ó mọ ohun tó wà nínú èèyàn.+
24 Àmọ́ Jésù ò gbára lé wọn, torí pé ó mọ gbogbo wọn, 25 kò sì nílò kí ẹnikẹ́ni jẹ́rìí nípa èèyàn, torí ó mọ ohun tó wà nínú èèyàn.+