ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 24:20, 21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ẹ̀mí Ọlọ́run bà lé* Sekaráyà ọmọ àlùfáà Jèhóádà,+ ó dúró sórí ibi tó ga láàárín àwọn èèyàn náà, ó sì sọ fún wọn pé: “Ohun tí Ọlọ́run tòótọ́ sọ nìyí, ‘Kí ló dé tí ẹ fi ń tẹ àwọn àṣẹ Jèhófà lójú? Ẹ ò ní ṣàṣeyọrí! Nítorí ẹ ti fi Jèhófà sílẹ̀, òun náà á sì fi yín sílẹ̀.’”+ 21 Àmọ́ wọ́n dìtẹ̀ mọ́ ọn,+ wọ́n sì sọ ọ́ lókùúta gẹ́gẹ́ bí àṣẹ ọba, ní àgbàlá ilé Jèhófà.+

  • Nehemáyà 9:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 “Àmọ́, wọ́n ya aláìgbọràn, wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọ,+ wọ́n sì kẹ̀yìn sí Òfin rẹ.* Wọ́n pa àwọn wòlíì rẹ tó kìlọ̀ fún wọn láti mú wọn pa dà sọ́dọ̀ rẹ, wọ́n sì hu ìwà àìlọ́wọ̀ tó bùáyà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́