Sáàmù 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Gbogbo àwọn tó ń rí mi ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;+Wọ́n ń yínmú, wọ́n sì ń mi orí wọn, pé:+