Àìsáyà 53:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n gún un+ torí àṣìṣe wa;+Wọ́n tẹ̀ ẹ́ rẹ́ torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+ Ó jìyà ká lè ní àlàáfíà,+A sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.+ Àìsáyà 53:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n ni ín lára,+ ó sì jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun,+Àmọ́ kò la ẹnu rẹ̀. Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,+Bí abo àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀,Kò sì la ẹnu rẹ̀.+
5 Wọ́n gún un+ torí àṣìṣe wa;+Wọ́n tẹ̀ ẹ́ rẹ́ torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa.+ Ó jìyà ká lè ní àlàáfíà,+A sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.+
7 Wọ́n ni ín lára,+ ó sì jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun,+Àmọ́ kò la ẹnu rẹ̀. Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,+Bí abo àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀,Kò sì la ẹnu rẹ̀.+