-
Mátíù 24:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ó sọ fún wọn pé: “Ṣebí ẹ rí gbogbo nǹkan yìí? Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, ó dájú pé wọn ò ní fi òkúta kan sílẹ̀ lórí òkúta míì níbí, láìwó o palẹ̀.”+
-
-
Lúùkù 21:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 ó sọ pé: “Ní ti àwọn nǹkan yìí tí ẹ̀ ń rí báyìí, ọjọ́ ń bọ̀ tí wọn ò ní fi òkúta kan sílẹ̀ lórí òkúta míì láìwó o palẹ̀.”+
-