Mátíù 24:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Torí orílẹ̀-èdè máa dìde sí orílẹ̀-èdè àti ìjọba sí ìjọba,+ àìtó oúnjẹ+ àti ìmìtìtì ilẹ̀ sì máa wà láti ibì kan dé ibòmíì.+ Máàkù 13:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Torí orílẹ̀-èdè máa dìde sí orílẹ̀-èdè àti ìjọba sí ìjọba;+ ìmìtìtì ilẹ̀ máa wà láti ibì kan dé ibòmíì; àìtó oúnjẹ náà máa wà.+ Àwọn nǹkan yìí jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ wàhálà tó ń fa ìrora.+
7 “Torí orílẹ̀-èdè máa dìde sí orílẹ̀-èdè àti ìjọba sí ìjọba,+ àìtó oúnjẹ+ àti ìmìtìtì ilẹ̀ sì máa wà láti ibì kan dé ibòmíì.+
8 “Torí orílẹ̀-èdè máa dìde sí orílẹ̀-èdè àti ìjọba sí ìjọba;+ ìmìtìtì ilẹ̀ máa wà láti ibì kan dé ibòmíì; àìtó oúnjẹ náà máa wà.+ Àwọn nǹkan yìí jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ wàhálà tó ń fa ìrora.+