Sekaráyà 11:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ni mo bá sọ fún wọn pé: “Tó bá dára lójú yín, ẹ fún mi ní owó iṣẹ́; tí kò bá sì dára lójú yín, ẹ mú un dání.” Wọ́n sì san* owó iṣẹ́ mi, ó jẹ́ ọgbọ̀n (30) ẹyọ fàdákà.+
12 Ni mo bá sọ fún wọn pé: “Tó bá dára lójú yín, ẹ fún mi ní owó iṣẹ́; tí kò bá sì dára lójú yín, ẹ mú un dání.” Wọ́n sì san* owó iṣẹ́ mi, ó jẹ́ ọgbọ̀n (30) ẹyọ fàdákà.+