Mátíù 19:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Jésù sọ fún wọn pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, nígbà àtúndá, tí Ọmọ èèyàn bá jókòó sórí ìtẹ́ ògo rẹ̀, ẹ̀yin tí ẹ ti tẹ̀ lé mi máa jókòó sórí ìtẹ́ méjìlá (12), ẹ sì máa ṣèdájọ́ ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì.+
28 Jésù sọ fún wọn pé: “Lóòótọ́ ni mo sọ fún yín, nígbà àtúndá, tí Ọmọ èèyàn bá jókòó sórí ìtẹ́ ògo rẹ̀, ẹ̀yin tí ẹ ti tẹ̀ lé mi máa jókòó sórí ìtẹ́ méjìlá (12), ẹ sì máa ṣèdájọ́ ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì.+