Máàkù 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jésù wá sọ fún wọn pé: “Ẹ san àwọn ohun ti Késárì pa dà fún Késárì,+ àmọ́ ẹ fi àwọn ohun ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”+ Ẹnu sì yà wọ́n sí i.
17 Jésù wá sọ fún wọn pé: “Ẹ san àwọn ohun ti Késárì pa dà fún Késárì,+ àmọ́ ẹ fi àwọn ohun ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”+ Ẹnu sì yà wọ́n sí i.