Jòhánù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà tí a wá jí i dìde, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ rántí pé ó máa ń sọ bẹ́ẹ̀,+ wọ́n sì gba ìwé mímọ́ àti ohun tí Jésù sọ gbọ́.
22 Nígbà tí a wá jí i dìde, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ rántí pé ó máa ń sọ bẹ́ẹ̀,+ wọ́n sì gba ìwé mímọ́ àti ohun tí Jésù sọ gbọ́.