Lúùkù 24:6-8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kò sí níbí, a ti gbé e dìde. Ẹ rántí bó ṣe bá yín sọ̀rọ̀ nígbà tó wà ní Gálílì, 7 tó sọ pé a gbọ́dọ̀ fi Ọmọ èèyàn lé àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ lọ́wọ́, kí wọ́n kàn án mọ́gi, kó sì dìde ní ọjọ́ kẹta.”+ 8 Wọ́n wá rántí àwọn ọ̀rọ̀ rẹ̀,+
6 Kò sí níbí, a ti gbé e dìde. Ẹ rántí bó ṣe bá yín sọ̀rọ̀ nígbà tó wà ní Gálílì, 7 tó sọ pé a gbọ́dọ̀ fi Ọmọ èèyàn lé àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ lọ́wọ́, kí wọ́n kàn án mọ́gi, kó sì dìde ní ọjọ́ kẹta.”+ 8 Wọ́n wá rántí àwọn ọ̀rọ̀ rẹ̀,+