-
Ìṣe 2:46, 47Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 Láti ọjọ́ dé ọjọ́, wọ́n ń pésẹ̀ déédéé sí tẹ́ńpìlì pẹ̀lú èrò tó ṣọ̀kan, wọ́n ń jẹun ní ilé ara wọn, wọ́n sì ń fi ayọ̀ púpọ̀ àti òótọ́ ọkàn pín oúnjẹ fún ara wọn, 47 wọ́n ń yin Ọlọ́run, wọ́n sì ń rí ojú rere lọ́dọ̀ gbogbo èèyàn. Lẹ́sẹ̀ kan náà, Jèhófà* ń mú kí àwọn tó ń rí ìgbàlà dara pọ̀ mọ́ wọn lójoojúmọ́.+
-