ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ìṣe 5:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ṣe ni àwọn onígbàgbọ́ nínú Olúwa ń dara pọ̀ mọ́ wọn, iye wọn sì pọ̀ lọ́kùnrin àti lóbìnrin.+

  • Ìṣe 11:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Yàtọ̀ síyẹn, ọwọ́ Jèhófà* wà lára wọn, ọ̀pọ̀ èèyàn di onígbàgbọ́, wọ́n sì yíjú sí Olúwa.+

  • 1 Kọ́ríńtì 3:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 tó fi jẹ́ pé kì í ṣe ẹni tó ń gbìn ló ṣe pàtàkì tàbí ẹni tó ń bomi rin, bí kò ṣe Ọlọ́run tó ń mú kó dàgbà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́