Jòhánù 6:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 torí mi ò sọ̀ kalẹ̀ wá láti ọ̀run+ kí n lè ṣe ìfẹ́ ara mi, ṣùgbọ́n láti ṣe ìfẹ́ ẹni tó rán mi.+