Mátíù 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jésù wá sọ fún ọ̀gágun náà pé: “Máa lọ. Bí o ṣe fi hàn pé o nígbàgbọ́, kó rí bẹ́ẹ̀ fún ọ.”+ Ara ìránṣẹ́ náà sì yá ní wákàtí yẹn.+ Máàkù 7:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ó wá sọ fún un pé: “Torí ohun tí o sọ yìí, máa lọ; ẹ̀mí èṣù náà ti kúrò lára ọmọbìnrin rẹ.”+ 30 Torí náà, ó lọ sí ilé rẹ̀, ó sì rí i tí ọmọ kékeré náà dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn, ẹ̀mí èṣù náà ti kúrò lára rẹ̀.+
13 Jésù wá sọ fún ọ̀gágun náà pé: “Máa lọ. Bí o ṣe fi hàn pé o nígbàgbọ́, kó rí bẹ́ẹ̀ fún ọ.”+ Ara ìránṣẹ́ náà sì yá ní wákàtí yẹn.+
29 Ó wá sọ fún un pé: “Torí ohun tí o sọ yìí, máa lọ; ẹ̀mí èṣù náà ti kúrò lára ọmọbìnrin rẹ.”+ 30 Torí náà, ó lọ sí ilé rẹ̀, ó sì rí i tí ọmọ kékeré náà dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn, ẹ̀mí èṣù náà ti kúrò lára rẹ̀.+