ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 4:42-44
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Ọkùnrin kan wá láti Baali-ṣálíṣà,+ ó sì kó ogún (20) búrẹ́dì ọkà bálì+ tí wọ́n fi àkọ́so èso ṣe àti àpò ọkà+ tuntun wá. Ìgbà náà ni Èlíṣà sọ pé: “Kó wọn fún àwọn èèyàn náà kí wọ́n lè jẹun.” 43 Síbẹ̀, ìránṣẹ́ rẹ̀ sọ pé: “Báwo ni màá ṣe gbé nǹkan yìí síwájú ọgọ́rùn-ún (100) èèyàn?”+ Ó fèsì pé: “Kó wọn fún àwọn èèyàn náà kí wọ́n lè jẹun, nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Wọ́n á jẹ, á sì tún ṣẹ́ kù.’”+ 44 Ni ó bá gbé e síwájú wọn, wọ́n jẹ, ó sì tún ṣẹ́ kù+ gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́