Jòhánù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹnikẹ́ni tó bá mu látinú omi tí màá fún un, òùngbẹ ò ní gbẹ ẹ́ láé,+ àmọ́ omi tí màá fún un á di ìsun omi nínú rẹ̀, á sì máa tú yàà jáde láti fúnni ní ìyè àìnípẹ̀kun.”+ Jòhánù 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Èyí túmọ̀ sí ìyè àìnípẹ̀kun,+ pé kí wọ́n wá mọ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo*+ àti Jésù Kristi,+ ẹni tí o rán. Róòmù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí ikú ni èrè* ẹ̀ṣẹ̀,+ àmọ́ ìyè àìnípẹ̀kun ni ẹ̀bùn tí Ọlọ́run ń fúnni+ nípasẹ̀ Kristi Jésù Olúwa wa.+
14 Ẹnikẹ́ni tó bá mu látinú omi tí màá fún un, òùngbẹ ò ní gbẹ ẹ́ láé,+ àmọ́ omi tí màá fún un á di ìsun omi nínú rẹ̀, á sì máa tú yàà jáde láti fúnni ní ìyè àìnípẹ̀kun.”+
3 Èyí túmọ̀ sí ìyè àìnípẹ̀kun,+ pé kí wọ́n wá mọ ìwọ Ọlọ́run tòótọ́ kan ṣoṣo*+ àti Jésù Kristi,+ ẹni tí o rán.
23 Nítorí ikú ni èrè* ẹ̀ṣẹ̀,+ àmọ́ ìyè àìnípẹ̀kun ni ẹ̀bùn tí Ọlọ́run ń fúnni+ nípasẹ̀ Kristi Jésù Olúwa wa.+