Jòhánù 6:65 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 65 Ó ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Ìdí nìyí tí mo fi sọ fún yín pé, kò sí ẹni tó lè wá sọ́dọ̀ mi láìjẹ́ pé Baba yọ̀ǹda fún un.”+
65 Ó ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Ìdí nìyí tí mo fi sọ fún yín pé, kò sí ẹni tó lè wá sọ́dọ̀ mi láìjẹ́ pé Baba yọ̀ǹda fún un.”+