Jòhánù 6:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Kò sí èèyàn tó lè wá sọ́dọ̀ mi láìjẹ́ pé Baba tó rán mi fà á,+ màá sì jí i dìde ní ọjọ́ ìkẹyìn.+