Jòhánù 8:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ibi ìṣúra+ ló ti sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí nígbà tó ń kọ́ni nínú tẹ́ńpìlì. Àmọ́ kò sẹ́ni tó mú un, torí wákàtí rẹ̀ ò tíì tó.+
20 Ibi ìṣúra+ ló ti sọ àwọn ọ̀rọ̀ yìí nígbà tó ń kọ́ni nínú tẹ́ńpìlì. Àmọ́ kò sẹ́ni tó mú un, torí wákàtí rẹ̀ ò tíì tó.+