ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 26:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Nígbà tí Jésù wà ní Bẹ́tánì, ní ilé Símónì adẹ́tẹ̀,+ 7 obìnrin kan tó ní orùba* alabásítà tí wọ́n rọ òróró onílọ́fínńdà olówó iyebíye sí wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í da òróró náà sí orí rẹ̀ nígbà tó ń jẹun.*

  • Máàkù 14:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nígbà tó wà ní Bẹ́tánì, tó ń jẹun* ní ilé Símónì adẹ́tẹ̀, obìnrin kan mú orùba* alabásítà tí wọ́n rọ òróró onílọ́fínńdà sí wá, ojúlówó náádì tó wọ́n gan-an ni. Ó já orùba alabásítà náà, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í da òróró náà sórí rẹ̀.+

  • Jòhánù 12:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Màríà wá mú ìwọ̀n pọ́n-ùn kan* òróró onílọ́fínńdà, ojúlówó náádì tó wọ́n gan-an, ó dà á sí ẹsẹ̀ Jésù, ó sì fi irun orí rẹ̀ nu ẹsẹ̀ rẹ̀ gbẹ. Òórùn òróró onílọ́fínńdà náà wá gba inú ilé náà kan.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́