Àìsáyà 53:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Ta ló ti nígbàgbọ́ nínú ohun tó gbọ́ lọ́dọ̀ wa?*+ Ní ti apá Jèhófà,+ ta la ti fi hàn?+