ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 40:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 A máa ṣí ògo Jèhófà payá,+

      Gbogbo ẹran ara* sì jọ máa rí i,+

      Torí Jèhófà ti fi ẹnu ara rẹ̀ sọ ọ́.”

  • Jòhánù 12:37, 38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé ó ti ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì níwájú wọn, wọn ò ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀, 38 kí ọ̀rọ̀ wòlíì Àìsáyà lè ṣẹ, ẹni tó sọ pé: “Jèhófà,* ta ló ti nígbàgbọ́ nínú ohun tó gbọ́ lọ́dọ̀ wa?*+ Ní ti apá Jèhófà,* ta la ti ṣí i payá fún?”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́