Jòhánù 19:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Torí náà, nígbà tí Jésù rí ìyá rẹ̀ àti ọmọ ẹ̀yìn tó nífẹ̀ẹ́,+ tí wọ́n dúró nítòsí, ó sọ fún ìyá rẹ̀ pé: “Obìnrin, wò ó! Ọmọ rẹ!” Jòhánù 20:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ló bá sáré wá bá Símónì Pétérù àti ọmọ ẹ̀yìn kejì, ẹni tí Jésù nífẹ̀ẹ́ gan-an,+ ó sì sọ fún wọn pé: “Wọ́n ti gbé Olúwa kúrò nínú ibojì,+ a ò sì mọ ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí.”
26 Torí náà, nígbà tí Jésù rí ìyá rẹ̀ àti ọmọ ẹ̀yìn tó nífẹ̀ẹ́,+ tí wọ́n dúró nítòsí, ó sọ fún ìyá rẹ̀ pé: “Obìnrin, wò ó! Ọmọ rẹ!”
2 Ló bá sáré wá bá Símónì Pétérù àti ọmọ ẹ̀yìn kejì, ẹni tí Jésù nífẹ̀ẹ́ gan-an,+ ó sì sọ fún wọn pé: “Wọ́n ti gbé Olúwa kúrò nínú ibojì,+ a ò sì mọ ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí.”