ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jòhánù 13:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ẹ̀yìn, ẹni tí Jésù nífẹ̀ẹ́,+ jókòó* sí tòsí* Jésù.

  • Jòhánù 21:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ni ọmọ ẹ̀yìn tí Jésù nífẹ̀ẹ́+ bá sọ fún Pétérù pé: “Olúwa ni!” Bí Símónì Pétérù ṣe gbọ́ pé Olúwa ni, ó wọ aṣọ àwọ̀lékè rẹ̀,* torí pé ìhòòhò ló wà,* ó sì bẹ́ sínú òkun.

  • Jòhánù 21:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Pétérù yíjú pa dà, ó sì rí ọmọ ẹ̀yìn tí Jésù nífẹ̀ẹ́+ tó ń tẹ̀ lé e, òun ló fẹ̀yìn ti àyà rẹ̀ níbi oúnjẹ alẹ́, tó sì sọ pé: “Olúwa, ta ló máa dà ọ́?”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́