Jòhánù 13:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ẹ̀yìn, ẹni tí Jésù nífẹ̀ẹ́,+ jókòó* sí tòsí* Jésù. Jòhánù 20:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ló bá sáré wá bá Símónì Pétérù àti ọmọ ẹ̀yìn kejì, ẹni tí Jésù nífẹ̀ẹ́ gan-an,+ ó sì sọ fún wọn pé: “Wọ́n ti gbé Olúwa kúrò nínú ibojì,+ a ò sì mọ ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí.”
2 Ló bá sáré wá bá Símónì Pétérù àti ọmọ ẹ̀yìn kejì, ẹni tí Jésù nífẹ̀ẹ́ gan-an,+ ó sì sọ fún wọn pé: “Wọ́n ti gbé Olúwa kúrò nínú ibojì,+ a ò sì mọ ibi tí wọ́n tẹ́ ẹ sí.”