ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jòhánù 16:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Mo ti sọ àwọn nǹkan yìí fún yín kí ẹ lè ní àlàáfíà nípasẹ̀ mi.+ Ẹ máa ní ìpọ́njú nínú ayé, àmọ́ ẹ mọ́kàn le! Mo ti ṣẹ́gun ayé.”+

  • Éfésù 2:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Nítorí òun ni àlàáfíà wa,+ ẹni tó ṣe àwùjọ méjèèjì ní ọ̀kan,+ tó sì wó ògiri tó pààlà sáàárín wọn.+

  • Fílípì 4:6, 7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ẹ má ṣe máa ṣàníyàn nípa ohunkóhun,+ àmọ́ nínú ohun gbogbo nípasẹ̀ àdúrà àti ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ pẹ̀lú ìdúpẹ́, ẹ máa sọ àwọn ohun tí ẹ̀ ń tọrọ fún Ọlọ́run;+ 7 àlàáfíà Ọlọ́run+ tó kọjá gbogbo òye yóò sì máa ṣọ́ ọkàn yín+ àti agbára ìrònú yín* nípasẹ̀ Kristi Jésù.

  • Kólósè 3:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Bákan náà, ẹ jẹ́ kí àlàáfíà Kristi jọba lọ́kàn yín,*+ nítorí a ti pè yín sínú àlàáfíà yẹn nínú ara kan. Torí náà, ẹ máa dúpẹ́.

  • 2 Tẹsalóníkà 3:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Tóò, kí Olúwa àlàáfíà máa fún yín ní àlàáfíà nígbà gbogbo àti ní gbogbo ọ̀nà.+ Kí Olúwa wà pẹ̀lú gbogbo yín.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́