Mátíù 11:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àti ìwọ, Kápánáúmù,+ ṣé a máa gbé ọ ga dé ọ̀run ni? Inú Isà Òkú* nísàlẹ̀ lo máa lọ;+ torí ká ní àwọn iṣẹ́ agbára tó ṣẹlẹ̀ nínú rẹ bá ṣẹlẹ̀ ní Sódómù ni, ì bá ṣì wà títí dòní yìí. Jòhánù 7:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Síbẹ̀, ọ̀pọ̀ nínú àwọn èèyàn náà gbà á gbọ́,+ wọ́n sì ń sọ pé: “Tí Kristi bá dé, ṣé ó máa ṣe iṣẹ́ àmì tó ju èyí tí ọkùnrin yìí ti ṣe lọ ni?” Jòhánù 11:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Torí náà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn Farisí kó Sàhẹ́ndìrìn jọ, wọ́n sì sọ pé: “Kí ni ká ṣe, torí ọkùnrin yìí ń ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì?+
23 Àti ìwọ, Kápánáúmù,+ ṣé a máa gbé ọ ga dé ọ̀run ni? Inú Isà Òkú* nísàlẹ̀ lo máa lọ;+ torí ká ní àwọn iṣẹ́ agbára tó ṣẹlẹ̀ nínú rẹ bá ṣẹlẹ̀ ní Sódómù ni, ì bá ṣì wà títí dòní yìí.
31 Síbẹ̀, ọ̀pọ̀ nínú àwọn èèyàn náà gbà á gbọ́,+ wọ́n sì ń sọ pé: “Tí Kristi bá dé, ṣé ó máa ṣe iṣẹ́ àmì tó ju èyí tí ọkùnrin yìí ti ṣe lọ ni?”
47 Torí náà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn Farisí kó Sàhẹ́ndìrìn jọ, wọ́n sì sọ pé: “Kí ni ká ṣe, torí ọkùnrin yìí ń ṣe ọ̀pọ̀ iṣẹ́ àmì?+