Jòhánù 7:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Jésù wá sọ pé: “Màá ṣì wà pẹ̀lú yín fúngbà díẹ̀ sí i, kí n tó lọ sọ́dọ̀ Ẹni tó rán mi.+ Jòhánù 14:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ní ìgbà díẹ̀ sí i, ayé ò ní rí mi mọ́, àmọ́ ẹ máa rí mi,+ torí pé mo wà láàyè, ẹ sì máa wà láàyè.