Jòhánù 4:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Jésù sọ fún wọn pé: “Oúnjẹ mi ni pé kí n ṣe ìfẹ́ ẹni tó rán mi,+ kí n sì parí iṣẹ́ rẹ̀.+