Kólósè 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó gbà wá lọ́wọ́ àṣẹ òkùnkùn,+ ó sì mú wa lọ sínú ìjọba Ọmọ rẹ̀ ọ̀wọ́n,