2 Síwájú sí i, Ọlọ́run sọ yín di ààyè, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ ti kú nínú àṣemáṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ yín,+ 2 nínú èyí tí ẹ ti rìn nígbà kan rí lọ́nà ti ètò àwọn nǹkan ayé yìí,+ lọ́nà ti ẹni tó ń darí àṣẹ afẹ́fẹ́,+ ẹ̀mí+ tó ń ṣiṣẹ́ nísinsìnyí nínú àwọn ọmọ aláìgbọràn.