Jòhánù 7:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ kò sí ẹni tó lè sọ̀rọ̀ rẹ̀ ní gbangba torí wọ́n ń bẹ̀rù àwọn Júù.+ Jòhánù 9:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ohun tó mú kí àwọn òbí rẹ̀ sọ àwọn nǹkan yìí ni pé wọ́n ń bẹ̀rù àwọn Júù,+ torí àwọn Júù ti fohùn ṣọ̀kan tẹ́lẹ̀ pé, tí ẹnikẹ́ni bá gbà pé òun ni Kristi, wọ́n máa lé ẹni yẹn kúrò nínú sínágọ́gù.+
22 Ohun tó mú kí àwọn òbí rẹ̀ sọ àwọn nǹkan yìí ni pé wọ́n ń bẹ̀rù àwọn Júù,+ torí àwọn Júù ti fohùn ṣọ̀kan tẹ́lẹ̀ pé, tí ẹnikẹ́ni bá gbà pé òun ni Kristi, wọ́n máa lé ẹni yẹn kúrò nínú sínágọ́gù.+