Mátíù 10:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá sẹ́ mi níwájú àwọn èèyàn, èmi náà máa sẹ́ ẹ níwájú Baba mi tó wà ní ọ̀run.+ Hébérù 10:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Báwo lẹ ṣe wá rò pé ó yẹ kí ìyà tó máa jẹ ẹni tó tẹ Ọmọ Ọlọ́run mọ́lẹ̀ pọ̀ tó, tó ti ka ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú+ tí a fi sọ ọ́ di mímọ́ sí nǹkan yẹpẹrẹ, tó sì fi ìwà àfojúdi mú ẹ̀mí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí bínú?+
29 Báwo lẹ ṣe wá rò pé ó yẹ kí ìyà tó máa jẹ ẹni tó tẹ Ọmọ Ọlọ́run mọ́lẹ̀ pọ̀ tó, tó ti ka ẹ̀jẹ̀ májẹ̀mú+ tí a fi sọ ọ́ di mímọ́ sí nǹkan yẹpẹrẹ, tó sì fi ìwà àfojúdi mú ẹ̀mí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí bínú?+