Lúùkù 24:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó wá bẹ̀rẹ̀ látọ̀dọ̀ Mósè àti gbogbo àwọn Wòlíì,+ ó sì túmọ̀ àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ òun fúnra rẹ̀ nínú gbogbo Ìwé Mímọ́ fún wọn. Ìṣe 10:43 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Òun ni gbogbo àwọn wòlíì jẹ́rìí sí,+ pé gbogbo ẹni tó bá gbà á gbọ́ máa rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà nípasẹ̀ orúkọ rẹ̀.”+
27 Ó wá bẹ̀rẹ̀ látọ̀dọ̀ Mósè àti gbogbo àwọn Wòlíì,+ ó sì túmọ̀ àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ òun fúnra rẹ̀ nínú gbogbo Ìwé Mímọ́ fún wọn.
43 Òun ni gbogbo àwọn wòlíì jẹ́rìí sí,+ pé gbogbo ẹni tó bá gbà á gbọ́ máa rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà nípasẹ̀ orúkọ rẹ̀.”+