Lúùkù 24:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó wá bẹ̀rẹ̀ látọ̀dọ̀ Mósè àti gbogbo àwọn Wòlíì,+ ó sì túmọ̀ àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ òun fúnra rẹ̀ nínú gbogbo Ìwé Mímọ́ fún wọn. Ìfihàn 19:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ni mo bá wólẹ̀ níwájú ẹsẹ̀ rẹ̀ láti jọ́sìn rẹ̀. Àmọ́ ó sọ fún mi pé: “Ṣọ́ra! Má ṣe bẹ́ẹ̀!+ Ẹrú bíi tìẹ ni mí àti ti àwọn arákùnrin rẹ tí iṣẹ́ wọn jẹ́ láti jẹ́rìí nípa Jésù.+ Ọlọ́run ni kí o jọ́sìn!+ Torí ìjẹ́rìí nípa Jésù ló ń mí sí àsọtẹ́lẹ̀.”+
27 Ó wá bẹ̀rẹ̀ látọ̀dọ̀ Mósè àti gbogbo àwọn Wòlíì,+ ó sì túmọ̀ àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ òun fúnra rẹ̀ nínú gbogbo Ìwé Mímọ́ fún wọn.
10 Ni mo bá wólẹ̀ níwájú ẹsẹ̀ rẹ̀ láti jọ́sìn rẹ̀. Àmọ́ ó sọ fún mi pé: “Ṣọ́ra! Má ṣe bẹ́ẹ̀!+ Ẹrú bíi tìẹ ni mí àti ti àwọn arákùnrin rẹ tí iṣẹ́ wọn jẹ́ láti jẹ́rìí nípa Jésù.+ Ọlọ́run ni kí o jọ́sìn!+ Torí ìjẹ́rìí nípa Jésù ló ń mí sí àsọtẹ́lẹ̀.”+