Ìṣe 5:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Ni wọ́n bá gba ìmọ̀ràn rẹ̀, wọ́n sì pe àwọn àpọ́sítélì, wọ́n nà wọ́n lẹ́gba,*+ wọ́n sì pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n má sọ̀rọ̀ nípa orúkọ Jésù mọ́, wọ́n wá fi wọ́n sílẹ̀.
40 Ni wọ́n bá gba ìmọ̀ràn rẹ̀, wọ́n sì pe àwọn àpọ́sítélì, wọ́n nà wọ́n lẹ́gba,*+ wọ́n sì pàṣẹ fún wọn pé kí wọ́n má sọ̀rọ̀ nípa orúkọ Jésù mọ́, wọ́n wá fi wọ́n sílẹ̀.