Lúùkù 22:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin sì ń wá ọ̀nà tó máa dáa gan-an láti rẹ́yìn rẹ̀,+ torí wọ́n ń bẹ̀rù àwọn èèyàn.+ Ìṣe 5:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ni olórí ẹ̀ṣọ́ bá lọ pẹ̀lú àwọn ẹ̀ṣọ́ rẹ̀, ó sì mú àwọn àpọ́sítélì wọlé, àmọ́ kì í ṣe tipátipá, torí wọ́n ń bẹ̀rù kí àwọn èèyàn má lọ sọ wọ́n lókùúta.+
2 Àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin sì ń wá ọ̀nà tó máa dáa gan-an láti rẹ́yìn rẹ̀,+ torí wọ́n ń bẹ̀rù àwọn èèyàn.+
26 Ni olórí ẹ̀ṣọ́ bá lọ pẹ̀lú àwọn ẹ̀ṣọ́ rẹ̀, ó sì mú àwọn àpọ́sítélì wọlé, àmọ́ kì í ṣe tipátipá, torí wọ́n ń bẹ̀rù kí àwọn èèyàn má lọ sọ wọ́n lókùúta.+