Mátíù 28:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! ìmìtìtì ilẹ̀ kan tó lágbára ti ṣẹlẹ̀, torí áńgẹ́lì Jèhófà* ti sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run, ó ti wá yí òkúta náà kúrò, ó sì jókòó sórí rẹ̀.+ 3 Ìrísí rẹ̀ rí bíi mànàmáná, aṣọ rẹ̀ sì funfun bíi yìnyín.+
2 Wò ó! ìmìtìtì ilẹ̀ kan tó lágbára ti ṣẹlẹ̀, torí áńgẹ́lì Jèhófà* ti sọ̀ kalẹ̀ láti ọ̀run, ó ti wá yí òkúta náà kúrò, ó sì jókòó sórí rẹ̀.+ 3 Ìrísí rẹ̀ rí bíi mànàmáná, aṣọ rẹ̀ sì funfun bíi yìnyín.+