Ìṣe 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Sọ́ọ̀lù, ní tirẹ̀, fọwọ́ sí bí wọ́n ṣe pa Sítéfánù.+ Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe inúnibíni tó lágbára sí ìjọ tó wà ní Jerúsálẹ́mù; gbogbo àwọn ọmọ ẹ̀yìn tú ká lọ sí gbogbo agbègbè Jùdíà àti Samáríà, àwọn àpọ́sítélì nìkan ni kò tú ká.+ Ìṣe 22:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 nígbà tí wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ Sítéfánù ẹlẹ́rìí rẹ sílẹ̀, mo wà níbẹ̀, mo fọwọ́ sí i, mo sì ń ṣọ́ aṣọ àwọ̀lékè àwọn tí ó pa á.’+
8 Sọ́ọ̀lù, ní tirẹ̀, fọwọ́ sí bí wọ́n ṣe pa Sítéfánù.+ Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe inúnibíni tó lágbára sí ìjọ tó wà ní Jerúsálẹ́mù; gbogbo àwọn ọmọ ẹ̀yìn tú ká lọ sí gbogbo agbègbè Jùdíà àti Samáríà, àwọn àpọ́sítélì nìkan ni kò tú ká.+
20 nígbà tí wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ Sítéfánù ẹlẹ́rìí rẹ sílẹ̀, mo wà níbẹ̀, mo fọwọ́ sí i, mo sì ń ṣọ́ aṣọ àwọ̀lékè àwọn tí ó pa á.’+