Ìṣe 11:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nígbà náà, àwọn tí ìpọ́njú tó wáyé nítorí Sítéfánù mú kí wọ́n tú ká+ ń lọ títí dé Foníṣíà, Sápírọ́sì àti Áńtíókù, àmọ́ àwọn Júù nìkan ni wọ́n ń wàásù fún.+
19 Nígbà náà, àwọn tí ìpọ́njú tó wáyé nítorí Sítéfánù mú kí wọ́n tú ká+ ń lọ títí dé Foníṣíà, Sápírọ́sì àti Áńtíókù, àmọ́ àwọn Júù nìkan ni wọ́n ń wàásù fún.+