Mátíù 10:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn méjìlá (12) yìí ni Jésù rán jáde, ó fún wọn ní àwọn ìtọ́ni yìí:+ “Ẹ má lọ sí ojú ọ̀nà àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ má sì wọ ìlú Samáríà kankan;+ 6 kàkà bẹ́ẹ̀, léraléra ni kí ẹ máa lọ sọ́dọ̀ àwọn àgùntàn ilé Ísírẹ́lì tó sọ nù.+
5 Àwọn méjìlá (12) yìí ni Jésù rán jáde, ó fún wọn ní àwọn ìtọ́ni yìí:+ “Ẹ má lọ sí ojú ọ̀nà àwọn orílẹ̀-èdè, ẹ má sì wọ ìlú Samáríà kankan;+ 6 kàkà bẹ́ẹ̀, léraléra ni kí ẹ máa lọ sọ́dọ̀ àwọn àgùntàn ilé Ísírẹ́lì tó sọ nù.+