Máàkù 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó wá pe àwọn Méjìlá náà, ó bẹ̀rẹ̀ sí í rán wọn jáde ní méjì-méjì,+ ó sì fún wọn láṣẹ lórí àwọn ẹ̀mí àìmọ́.+ Lúùkù 9:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó wá pe àwọn Méjìlá náà jọ, ó fún wọn ní agbára àti àṣẹ lórí gbogbo ẹ̀mí èṣù,+ kí wọ́n sì máa ṣe ìwòsàn.+ 2 Ó rán wọn jáde láti wàásù Ìjọba Ọlọ́run, kí wọ́n sì máa múni lára dá,
7 Ó wá pe àwọn Méjìlá náà, ó bẹ̀rẹ̀ sí í rán wọn jáde ní méjì-méjì,+ ó sì fún wọn láṣẹ lórí àwọn ẹ̀mí àìmọ́.+
9 Ó wá pe àwọn Méjìlá náà jọ, ó fún wọn ní agbára àti àṣẹ lórí gbogbo ẹ̀mí èṣù,+ kí wọ́n sì máa ṣe ìwòsàn.+ 2 Ó rán wọn jáde láti wàásù Ìjọba Ọlọ́run, kí wọ́n sì máa múni lára dá,