Hébérù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Bákan náà, ó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì pé: “Ó dá àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mí, ó sì dá àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀*+ ní ọwọ́ iná.”+ Hébérù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ṣebí ẹ̀mí tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́*+ ni gbogbo wọn, tí a rán jáde láti ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn tó máa rí ìgbàlà? Ìfihàn 14:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mo rí áńgẹ́lì míì tó ń fò lójú ọ̀run,* ó ní ìhìn rere àìnípẹ̀kun láti kéde fún àwọn tó ń gbé ayé, fún gbogbo orílẹ̀-èdè àti ẹ̀yà àti ahọ́n* àti èèyàn.+
7 Bákan náà, ó sọ nípa àwọn áńgẹ́lì pé: “Ó dá àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mí, ó sì dá àwọn òjíṣẹ́ rẹ̀*+ ní ọwọ́ iná.”+
14 Ṣebí ẹ̀mí tó ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́*+ ni gbogbo wọn, tí a rán jáde láti ṣe ìránṣẹ́ fún àwọn tó máa rí ìgbàlà?
6 Mo rí áńgẹ́lì míì tó ń fò lójú ọ̀run,* ó ní ìhìn rere àìnípẹ̀kun láti kéde fún àwọn tó ń gbé ayé, fún gbogbo orílẹ̀-èdè àti ẹ̀yà àti ahọ́n* àti èèyàn.+