-
Róòmù 2:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Nítorí kì í ṣe àwọn tó ń gbọ́ òfin ni olódodo níwájú Ọlọ́run, àmọ́ àwọn tó ń ṣe ohun tí òfin sọ ni a ó pè ní olódodo.+
-
-
1 Kọ́ríńtì 12:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Nítorí ipasẹ̀ ẹ̀mí kan ni a batisí gbogbo wa sínú ara kan, ì báà jẹ́ Júù tàbí Gíríìkì, ẹrú tàbí òmìnira, a sì mú kí gbogbo wa gba* ẹ̀mí kan.
-