Róòmù 10:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí kò sí ìyàtọ̀ nínú Júù àti Gíríìkì.+ Torí Olúwa kan náà ló wà lórí gbogbo wọn, ẹni tó lawọ́* sí gbogbo àwọn tó ń ké pè é.
12 Nítorí kò sí ìyàtọ̀ nínú Júù àti Gíríìkì.+ Torí Olúwa kan náà ló wà lórí gbogbo wọn, ẹni tó lawọ́* sí gbogbo àwọn tó ń ké pè é.